Bi o ba la Ala wipe eyin re yo tabi o kan. Opolopo eniyan ni o ma n la ala wipe eyin toun yo tabi eyin toun kan hmmmn Ala yi ni agbara pupo sugbon opolopo wa ni ao ka Ala yi si nkankan haaaa ayafi kio sora Olohun oba feran re lose ntu asiri fun e. Bio ba la ala wipe eyin re yo, Ala yi ntunmo si wipe kio sora pupo pupo pelu imafi enure se epe nitoripe eyin re loju ala ntunmo si Ase (Command), won so fun e wipe kio sora lati binu so oro odi nigba kugba boya ti ibinu bade, awon yoruba sowipe epe ti olu ife koko ra lojosi akobi omo lofi pa hmmnnn, sora lati so oro odi sinu igbesi aye awon omo re, okore, tabi alasunmo bi oloore re ki iwona maba padanu nkan meji tinse Ase enu re ati nkan pataki kan ninu igbesi aye re. Kiloma nfa iru ala bayi? Oun nani wipe Olohun oba fe jeki oso arare pelu opolopo Adura ijanu ati saara iso enu, ni awon yoruba fi sowipe ki eeyan lo bo enu re tinse oluboborotiribo awo enu. Eyin ase ati eyin onkan wa koni fiwale si aye lo ooo.
Igbiyanju lagba ohun gbogbo nile aye, nitoripe leyin igbiyanju lanmo kadara. Eniti oba gbiyanju yio ri nkan tonwa nile Aye...