Skip to main content

ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE




ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE, OYA GBO ITUSILE ORO

 
Mofe so oro nla kan fun awon oni lakaye mosi mo wipe eniti oba farabale yio gbomiye.......

1. Iwo ti o se eyonu awon agbalagba lati kekere titi tio fipe 45 years old laye ti o de sin se lo nitoripe won koti yonu sie na oori ile aye re yanju niyen tabi kin so wipe oori aye wa.

2. Iwo ti o se imule awon agba lati kekere re titi ti o fipe omo 45 years old ti o de sin lo lo nitoripe o si ninu egbe imule won yala ni ita abi ninu gangan oori ile aye wa.

3. Onse ipese awon agba lati kekere re titi tio fidi omo 45 years old lori oro igbesi aye re, igbesi aye re kosi bosi bio se fe oori ile aye wa.

4. Onse ebe awon agba lati kekere re bio Seun bebe Bena lotun se ese si won gba e mu won tun ju e le titi ti o fipe 45 years old o ti ye bebe lati jo joyi na oori ile aye wa. Haaaaaa ma so wipe aseku ni oo rara oo kinse aseku oo, ti bukata re bati biya oti biya nani yen oo, sise ti Otu ntunse bukata re tio ti biya ni ooo, ma jeki ete won mu e mole oo bi o base akiyesi daada wari wipe tio base aribi igbati ona fesi
fun o yio tu ti pada nitori kio bale tun se irure si fun won nio, olohun oba nikan la maun si ni asinku ooo, iwo ore mi fura oo, ifura lagba ogun oo, ifura logun agba pelu, kinse gbogbo wa laye ni awon nkan ti tosi oun lo se ndamu laye, elomiran nbe laye ori re ni agbara debi wipe apa aje kan kole ka, sugbon Hmmn komo arare o ma se oo, elomiran si nbe olorun féran re Debi wipe kofun edare kan laye wipe ki apare ka, sugbon o mase oo wipe koda arare mo, ati bebelo, orore wada bi eniti president ilu ni ife re gidi gan ti o tun wa loun fi ara gbole fun chairman local government lolzz, gbogbo oun ti awi kale yi beena ni ida keji re nbe oo, sugbon iwo ore mi gbiyanju kio mo iru eda eniyan ti iwo nse kio simo nkan ti eleda re nfe kio si mo ipore ni iwaju olohun ki o bale mo bio ti fese igbesi aye re oo. Oro si nbo lori bi o ti fe ma da arare mo die die. Otan lenu oku ni ikun, moun bowa mio tide.

Comments

  1. Bawo ni mo se le mo ara mi.
    E gba mi o

    ReplyDelete
    Replies
    1. ejowo kinni alfi mo asiri ti o bani lo gegebi ki eyan fe se oogun owo taara ti kosi nkan eewo nbe

      Delete

Post a Comment

TREADING...

ASIRI ATIBO NINU OGUN AYE (OWU ALANTAKUN)

OWO ALANTAKUN  Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe o nrin lo sugbon hmmmn..... Oku eeyan ni. Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe ije eeyan arare tifi sile sugbon ko mo. Haaaa. O mase oooo........ Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun dina fun eleda re sugbon o nsowipe ori o fomoun shaka lara toun da. Opolopo omo ile iwe ni alantakun aye ti takun di laakaye re. Hmmmmmm Aye toto....... Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun di ariziki re, won wa nfunni owo onje nikan, kosi mo wipe owo igbiyanju lori igbesi aye oun ni won fun oun ki oun bale wa nkan sesi igbesi aye oun. Haaaa owu alantakun, kole di igi kole di irin sugbon tiwon bafi di omo eeyan koleja. Iwo oremi toni anfani lati ma gbomi sare oooo komaba waye lasan, kio si ranti wipe olohun oda e lasan, maduro oooo nitoripe aye gan o duro lasan. Oyeki elomiiran ti ju bayi lo sugbon awu alantakun nko oooo. Owu alantakun ni won figbe elomiiran de ni ko jeki o kuro ni ipo kan bosi ipo gidi sugbon nitoripe o nlosi i...

ASIRI AYE (GBO ASIRI TOPAMO SI ARA OMO NLE)

IFURA NI OOGUN AGBA... Awon eda kan nbe ninu aye yi tose wipe tia batiri ninu ile kia mase fi ara le fun rara ooo nitoripe bad luck ati opolopo aarun, aisan ninbe lara re, nkan tosi fa po pupo sugbon ejekin so die nibe lati lefi se arawa ni anfaani. OMONLE je eranko kan tose wipe o je CID tabi kia sowipe iranse aburu, olofofo laarin awon alujonu ati eda eniyan, koda iranse awon apakan ninu awon emere ni pelu, bi won se nbe ni Aye nibi beena ni won be lodo awon alujonu na, eleyi lose okunfa fun awon alagbara tiwon da nkan mo ninu awon alujonu ati awa eeyan wipe eranko tobati dawapo iranse lo gbodo maje si arawa, latara bayi iwo omo iyaami loni akiyesi topo ati aifarale fun eranko yi ninu ile re nitoripe iranse buruku niooo. Bio ba njade lo laaro losi ibise tabi ibi nkan rere kan, ti ojure bari OMONLE yi haaaaa olewu fura ooo nitoripe apeere oro nla kan niyen ooo, won fe kio mu rere bo nibiti o nlo nioo. Bio baun bo lati ita tio wa pade OMONLE yi ninu ile gele bio se wole hmmmn n...