OWO ALANTAKUN
Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe o nrin lo sugbon hmmmn..... Oku eeyan ni. Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe ije eeyan arare tifi sile sugbon ko mo. Haaaa. O mase oooo........
Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun dina fun eleda re sugbon o nsowipe ori o fomoun shaka lara toun da.
Opolopo omo ile iwe ni alantakun aye ti takun di laakaye re. Hmmmmmm Aye toto.......
Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun di ariziki re, won wa nfunni owo onje nikan, kosi mo wipe owo igbiyanju lori igbesi aye oun ni won fun oun ki oun bale wa nkan sesi igbesi aye oun.
Haaaa owu alantakun, kole di igi kole di irin sugbon tiwon bafi di omo eeyan koleja.
Iwo oremi toni anfani lati ma gbomi sare oooo komaba waye lasan, kio si ranti wipe olohun oda e lasan, maduro oooo nitoripe aye gan o duro lasan.
Oyeki elomiiran ti ju bayi lo sugbon awu alantakun nko oooo.
Owu alantakun ni won figbe elomiiran de ni ko jeki o kuro ni ipo kan bosi ipo gidi sugbon nitoripe o nlosi ibise onbo owa ro. wipe oun ti kuro loju kan haaaaa oremi orore dami fan Tonyi loju kan ni ooo.
Olohun sowipe كل يوم هو في شأن oni oun duro nigba kankan ori ise loun wa.....iyen ni iwo walo duro haaa owu alantakun niyen ooo. Ya tete lo Sora nbe.
Alukinba Aso Agbara imo awon eni olohun.

I was with my boyfriend, I got intoxicated and started telling so many things, like I am omo omi, the ex girl Friend that refuse to leave him has charmed him that's why no matter who he love he always go back to this girl. Also that when we had a fight my egbe people were the one punishing him. But the problem is I found all this strange and I don't know if its true or its rubbish. Pls can u be of help sir
ReplyDeleteAm omo omi not drinking water( mistake in text)
DeleteI mean I am a water child...is it true? Pls I need answer cos am confuse n a little scared
DeleteWater girl
DeleteChat me up on WhatsApp via this number for better clarification about your question(+2347069414133)
Deletekin a lelo fun alatakan ye
ReplyDelete