Skip to main content

ASIRI AYE (GBO ASIRI TOPAMO SI ARA OMO NLE)

IFURA NI OOGUN AGBA...



Awon eda kan nbe ninu aye yi tose wipe tia batiri ninu ile kia mase fi ara le fun rara ooo nitoripe bad luck ati opolopo aarun, aisan ninbe lara re, nkan tosi fa po pupo sugbon ejekin so die nibe lati lefi se arawa ni anfaani.

OMONLE je eranko kan tose wipe o je CID tabi kia sowipe iranse aburu, olofofo laarin awon alujonu ati eda eniyan, koda iranse awon apakan ninu awon emere ni pelu, bi won se nbe ni Aye nibi beena ni won be lodo awon alujonu na, eleyi lose okunfa fun awon alagbara tiwon da nkan mo ninu awon alujonu ati awa eeyan wipe eranko tobati dawapo iranse lo gbodo maje si arawa, latara bayi iwo omo iyaami loni akiyesi topo ati aifarale fun eranko yi ninu ile re nitoripe iranse buruku niooo.

Bio ba njade lo laaro losi ibise tabi ibi nkan rere kan, ti ojure bari OMONLE yi haaaaa olewu fura ooo nitoripe apeere oro nla kan niyen ooo, won fe kio mu rere bo nibiti o nlo nioo.

Bio baun bo lati ita tio wa pade OMONLE yi ninu ile gele bio se wole hmmmn nkan ire tio mubo won fe kio wulo fun e nioo.

OMONLE yi ni iya lenu kan ni ara, tio bafe pa OMONLE ti oju iwo atire bati se deede arayin, otimo erongba okanre lekanna yiosi salo fun e, eleyi lofa tofi jewipe ti o bawa ninu ile ti o nronu lowo nipa aseyori lori nkankan tio bafi oju kan lasiko igbana hmmmnn, osese koma si aseyori rere lori nkan ti o ronu lelori ooo.

Bio bari OMONLE ni ile iwe nigbati ofe si ihoho re kale tabi ti otisi ihoho re kale hmmmn, kio lomo wipe kosi ifun kan tinbe ninu oromo adie ti awodi oke o mo, gbogbo igbesi ayere patapata titi kan awon erongba okanre ni yio lofi jise ni agbanla aye imiran lohun.

Oro po nibe sugbon je kin danu duro nibi nitoripe Agbalagba ki nko akotan orin, pelepele sini eegun agba njo.

Bi Oro mi bawa jo bi iro gbiyanju kio lobere ibeere yi lowo awon tiwon mo oogun ibile daada wipe ise wo gan ni won ma nfi OMONLE se? Won a da e lohun wipe ise ARIRAN ati AJATUKA ati beebelo hmmnnn Emi o mo nkankan nitemi ooo.

Emi Alukinba Aso Agbara imo Awon eni Olohun.

Comments

  1. E see oo E how kin Ia le fi segun omonile yi ninu Ile wa oo

    ReplyDelete
  2. Ona po repete lati dekun re. E bami soro Lori 09051800011

    ReplyDelete
  3. Kila wa lese lati segun ise aburu ti OMOONILE nse ninu ile tabi laye wa

    ReplyDelete

Post a Comment

TREADING...

ASIRI ATIBO NINU OGUN AYE (OWU ALANTAKUN)

OWO ALANTAKUN  Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe o nrin lo sugbon hmmmn..... Oku eeyan ni. Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe ije eeyan arare tifi sile sugbon ko mo. Haaaa. O mase oooo........ Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun dina fun eleda re sugbon o nsowipe ori o fomoun shaka lara toun da. Opolopo omo ile iwe ni alantakun aye ti takun di laakaye re. Hmmmmmm Aye toto....... Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun di ariziki re, won wa nfunni owo onje nikan, kosi mo wipe owo igbiyanju lori igbesi aye oun ni won fun oun ki oun bale wa nkan sesi igbesi aye oun. Haaaa owu alantakun, kole di igi kole di irin sugbon tiwon bafi di omo eeyan koleja. Iwo oremi toni anfani lati ma gbomi sare oooo komaba waye lasan, kio si ranti wipe olohun oda e lasan, maduro oooo nitoripe aye gan o duro lasan. Oyeki elomiiran ti ju bayi lo sugbon awu alantakun nko oooo. Owu alantakun ni won figbe elomiiran de ni ko jeki o kuro ni ipo kan bosi ipo gidi sugbon nitoripe o nlosi i...

ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE

ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE, OYA GBO ITUSILE ORO   Mofe so oro nla kan fun awon oni lakaye mosi mo wipe eniti oba farabale yio gbomiye....... 1. Iwo ti o se eyonu awon agbalagba lati kekere titi tio fipe 45 years old laye ti o de sin se lo nitoripe won koti yonu sie na oori ile aye re yanju niyen tabi kin so wipe oori aye wa. 2. Iwo ti o se imule awon agba lati kekere re titi ti o fipe omo 45 years old ti o de sin lo lo nitoripe o si ninu egbe imule won yala ni ita abi ninu gangan oori ile aye wa. 3. Onse ipese awon agba lati kekere re titi tio fidi omo 45 years old lori oro igbesi aye re, igbesi aye re kosi bosi bio se fe oori ile aye wa. 4. Onse ebe awon agba lati kekere re bio Seun bebe Bena lotun se ese si won gba e mu won tun ju e le titi ti o fipe 45 years old o ti ye bebe lati jo joyi na oori ile aye wa. Haaaaaa ma so wipe aseku ni oo rara oo kinse aseku oo, ti bukata re bati biya oti biya nani yen oo, sise ti Otu ntunse bukata re tio ti biya ni ooo, ma j...