Skip to main content

ALAYE LORI ALA LILA

ALA LILA

Omo iya mi mofe kio mo wipe Ala lila je ona pataki kan ti Olohun ma ngba ba eda re soro, oore nla nifun e bio bamo tunmo re sugbon aburu ni ooo ti o koba mo itunmo re.

Gbogbo botile hun ki enina je nitoripe Aanu Olohun to Kari aye ni ala lila je gbogbo eeyan sini yio ma lala ayafi awon kankan ti wahala ba nbefun emi won tabi eniti iyare ba nse nkan osu lori oyun re ati beebelo.

1.Ti ile bati su mase ma ro Ala fun eeyan nitoripe awon emi orisirisi tin jade nigbana won sile so oro ana di nkan imiran mo eeyan lowo.

2. Mase ma ro Ala fun enikeni toba ti ri, gbiyanju kio ro Ala re fun eniti o mo wipe oda e loju wipe o mo Ala tu daada nitoripe ti eeyan bafe ro Ala fun eeyan malaaika tinbe ni incharge Ala re yio sokale lati fi ase si nkan ti eniyi basi tu fun e nani yio se mo e lara...toba tu Ala daada fun e ni aburu hmmm aburu nani yio fe sele.

3. Gbiyanju kio trust eniti o fe ro Ala re fun wipe kio ba e tu nitoripe hmmmn awon eeyan nbe ti won tiri orire re latara Ala re tio ro funwon won a sise le lori wipe ki Ala na maba se. Eni a gbe oju okun le kojo a ni agba.. eniti a niki o fe ni loju a mafi ata senu ooo.

4. Mase ro Ala fun eeyan loju elomiran bi Alejo, ota re, Abi iyale iya re Abi iyawo iyare, won le maje ota re ooo Sugbon asiri re nani alare laarin iwo ati eniti o ba mu ni Alfa re, iya re, Baba re.

5. Gbiyanju kio se irori daada lori Ala re boya Emi re na le so nkan ti Olohun fi npa owe fun o.

Jeki nfi Ala yi se e ni Anfani.

Bio ba lala wipe onje nla nbe niwaju re bayi ti awon eeyan wa nwo e terin toyaya koda won tungbe camera tie hmmmn.

1. Iwo (iwo nani a fe ba soro kinse elomiran)

2. Onje repete topo ju e lo (eleyi a ma tunmo si oro tabi oore topo daada ninu igbesi aye re bi ariziki tio to iwo ati awon omo re lo laye koda ti won a tuma jogun re lo)

3. Awon eeyan repete (iyi ni eleyi ntunmo si, awon eeyan yio mo e daada latara ariziki yi)

4. Camera (Awon oju kan ninu awon eeyan repete yi yio ma so e koda won a tuma mu e sinu yala lori daada abi aburu)

5.terin toyaya (iyonu awon eeyan yio mabe lara re nitoripe olowo laye mo).

Oro po nibe Sugbon ki eleyi maje wonba soki.

Ikilo towa ninu alayi ni wipe....

1.Mase je aye awon omore mo aye kio bale ni eyin rere lojo ola. (Alajetan)

2. Mase je eeyan tose wipe afemi afemi, (greediness) Woobia...

3. Mase jaye debi wipe ki aye wamo asiri re latara ewu tio bo kale loju alayi. Ati beebelo.

Alukinba Aso imo.

Comments

TREADING...

ASIRI ATIBO NINU OGUN AYE (OWU ALANTAKUN)

OWO ALANTAKUN  Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe o nrin lo sugbon hmmmn..... Oku eeyan ni. Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe ije eeyan arare tifi sile sugbon ko mo. Haaaa. O mase oooo........ Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun dina fun eleda re sugbon o nsowipe ori o fomoun shaka lara toun da. Opolopo omo ile iwe ni alantakun aye ti takun di laakaye re. Hmmmmmm Aye toto....... Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun di ariziki re, won wa nfunni owo onje nikan, kosi mo wipe owo igbiyanju lori igbesi aye oun ni won fun oun ki oun bale wa nkan sesi igbesi aye oun. Haaaa owu alantakun, kole di igi kole di irin sugbon tiwon bafi di omo eeyan koleja. Iwo oremi toni anfani lati ma gbomi sare oooo komaba waye lasan, kio si ranti wipe olohun oda e lasan, maduro oooo nitoripe aye gan o duro lasan. Oyeki elomiiran ti ju bayi lo sugbon awu alantakun nko oooo. Owu alantakun ni won figbe elomiiran de ni ko jeki o kuro ni ipo kan bosi ipo gidi sugbon nitoripe o nlosi i...

ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE

ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE, OYA GBO ITUSILE ORO   Mofe so oro nla kan fun awon oni lakaye mosi mo wipe eniti oba farabale yio gbomiye....... 1. Iwo ti o se eyonu awon agbalagba lati kekere titi tio fipe 45 years old laye ti o de sin se lo nitoripe won koti yonu sie na oori ile aye re yanju niyen tabi kin so wipe oori aye wa. 2. Iwo ti o se imule awon agba lati kekere re titi ti o fipe omo 45 years old ti o de sin lo lo nitoripe o si ninu egbe imule won yala ni ita abi ninu gangan oori ile aye wa. 3. Onse ipese awon agba lati kekere re titi tio fidi omo 45 years old lori oro igbesi aye re, igbesi aye re kosi bosi bio se fe oori ile aye wa. 4. Onse ebe awon agba lati kekere re bio Seun bebe Bena lotun se ese si won gba e mu won tun ju e le titi ti o fipe 45 years old o ti ye bebe lati jo joyi na oori ile aye wa. Haaaaaa ma so wipe aseku ni oo rara oo kinse aseku oo, ti bukata re bati biya oti biya nani yen oo, sise ti Otu ntunse bukata re tio ti biya ni ooo, ma j...

ASIRI AYE (GBO ASIRI TOPAMO SI ARA OMO NLE)

IFURA NI OOGUN AGBA... Awon eda kan nbe ninu aye yi tose wipe tia batiri ninu ile kia mase fi ara le fun rara ooo nitoripe bad luck ati opolopo aarun, aisan ninbe lara re, nkan tosi fa po pupo sugbon ejekin so die nibe lati lefi se arawa ni anfaani. OMONLE je eranko kan tose wipe o je CID tabi kia sowipe iranse aburu, olofofo laarin awon alujonu ati eda eniyan, koda iranse awon apakan ninu awon emere ni pelu, bi won se nbe ni Aye nibi beena ni won be lodo awon alujonu na, eleyi lose okunfa fun awon alagbara tiwon da nkan mo ninu awon alujonu ati awa eeyan wipe eranko tobati dawapo iranse lo gbodo maje si arawa, latara bayi iwo omo iyaami loni akiyesi topo ati aifarale fun eranko yi ninu ile re nitoripe iranse buruku niooo. Bio ba njade lo laaro losi ibise tabi ibi nkan rere kan, ti ojure bari OMONLE yi haaaaa olewu fura ooo nitoripe apeere oro nla kan niyen ooo, won fe kio mu rere bo nibiti o nlo nioo. Bio baun bo lati ita tio wa pade OMONLE yi ninu ile gele bio se wole hmmmn n...