ELEYI NI ALAYE NI WONBA BOTI LE DA ARARE MO NI WONBA...........
Ninu gbogbo nkan laye OYE Se pataki pupo nitori wipe oye gangan lagba nwo, iwona gbiyanju ki o woye si arare latara awon nkankan ninu arare boya latara bayi iwona wa da arare mo, ti eniyan bawo ifa fun e kosi aburu nbe bi eniyan bawo iyepe fun e kosi aburu nbe sugbon lodo temi oo yato si ki eniti oun wo nko fun e lo Iriran tabi onmo Haaa oye ju gbogbo e lo oo nitoripe opolopo oun ti won ba so fun e oye loma fi gbe opolopo ninu e, latara bayi jowo bami woye si awon nkan ti mofe ka kale yi.
1. Ala ti o maun saba nla ni igba gbogbo, jowo se o maun Segun loju alare ni abi o kinsegun?
2. Se ala dada lo maun lani abi abi ala buruku. Bio bawa la ti aburu se o maun Segun?
3. Loju aye gangan se okan re maun bale lori igbesi aye re abi koda e loju?
4. Awon obi re inu ogun wo ni won wa abi se won kosi ninu ogun kankan?
5. Iyawo Melo ni baba re fe ipowo deni iya re wa laarin won. That will be competition among children.
6. Se olaya abi o laya rara?
7. Se awon eniyan maun beru re abi won ko kin beru re?
8. Se awon eniyan maun pon e le abi won kin pon e le?
9. Iwo gan funrarare woye si orun re ni ojo tiwon ba bie ni ojo ibire.
10. Se saara pelu gbogbo nkan funfun ni jije ni abi ni mimu ni, kio be olohun wipe tani mi gan.
Comments
Post a Comment