OJA TITA
Oro re nipa oja tita fun iwo onisowo oja tabi ise owo (handwork) lokunrin ati lobinrin.
Kilo ma nfa gan ki eeyan mase ta tabi ki eeyan mase mata Ata jere tabi ki a mari owo re koduro lowo lati fi se nkan ire hmmmn gbiyanju kio lo se akiyesi awon nkan won yi nitori ife ti emi Alukinba nisi gbogbo aye latara Olohun oba.
1. Osese kio je elegbe, ki awon egbere si maferan oja ti o nta, for example ije elegbe re romo ibi omi ti o ba nta awon iran eja kan yio ma bie leere Lori aje re. Elekeji nbe niwipe kio lomo saara toye fun awon egbere, lo gbiyanju lori eniti awon agbalagba npeni oko orun tabi oko oru eyi tose wipe yio wama ba e Sun loju ala, bi nkan yi ba nsele ariziki re yio ma se segesege. Ati beebelo.
2. Gbiyanju kio lomo iru ojo toba irawo re mu, boya irawo iyepe ni iwo nlo ni Abi irawo omi, ategun Abi ina. Eleyi ni yio so iru ise tio le se jere fun o. Eleyi ni yio jeki omo nkan eewo tiko yeki o maje si enure tabi kio mase, gbogbo awon nkan wonyi loni se pelu ariziki re ati wipe se oko re (husband) Abi iyawo toba irawo re mu ni ejo nse nitori wipe eniti o bati si ese gbe nibi iyawo tabi oko otisi ese gbe nibi gbogbo nkan ooo.
3. Osese kio jewipe awon Alagbara le jowa ni oja kio mamo tabi kiwon je olugbiyanju tosi nte igbiyanju tie mole hmmmnn odidi oro nioo, oro si po nibe. Awon oni lara tiwon nmu ejore kiri nbe ninu won, awon elegan nbe ninu won, ati beebelo tiwon je alagbara koda kiwon ma kuro loju kan.
Comments
Post a Comment