Skip to main content

AMORAN LORI OOGUN FUNFUN

OOGUN FUNFUN
Gbiyanju kio lomo nipa oogun funfun nitoripe gbogbo eeyan koni oogun dudu ba lara mu.

Oogun dudu yio

mu owo wafun eeyan sugbon kosi igbati o ni pada broke again nkan sini se pelu ariziki re oun lofa lofi je wipe ko gbodo maje nkan ojojumo, pele pele di owo wa. 

Sugbon oogun funfun ki nsebe kosi ni mu owo ojiji wa fun eeyan koda yio tuma lekun imole arare latara eelo ti abafise.

Apere eelo oogun funfun re kio bale mo wipe onbe gegebi Olohun base fi imo mo onikaluku wa.
  1. Omi okun ati iyepe re.
  2. Omi osa ati iyepe re. 
  3. Omi inu apata.
  4. Omi odo ti o nsan.
  5. Omi ojo oferefe. 
  6. Omi ara eeso (oloju eeso).
  7. Ose funfun balau bi joy Abi lux nigbamiran ose colour orisirisi yatosi black soap.
  8. Eja odo bi pakura tabi eja alawo funfun.
  9. Awo funfun balau tiko ni abawon. 
  10. Aso funfun.
  11. Lofinda to ni oorun daada tabi perfume. Awon ewe kan wa nbe mofi Olohun bura funfun niwon awon ewe kan sinbe tiwon je dudu ati awon colour imiran na hmmmn ona imo jin.


Nje o mo wipe oomi ojo oferefe tio bagbe ninu ni oganjo oru nje o mo wipe omi funfun ni asiri nbe nibe oro sipo nibe. Koda awon asiko funfun nbe awon asiko dudu nbe hmmnnn life is all about word and opposite.  

Nje o mo wipe eye funfun nbe fun awon Iran oogun funfun. 
Beena ni opolopo eelo ti opolopo wa kofi ojusi lara. 

Nje o mo wipe bi eeyan bafi oogun dudu koju asasi sio nje o mo wipe funfun lofe fi koju re lomo wipe aju arawa lo tija kadi ko, koda nibi ijakadi gan atuju arawa lo.

Nigbati o bati mo wipe irun tinbe lori re funfun na losi npada bo wadi hahaaaa fura ooo. Mofe la e loju niooo. Oro po nbe sugbon ejeki ada duro na nitori bia bani bi inu eni base tobi to lase fe ya iso haaaa nkan abaje.

Emi Alukinba Aso Agbara awon eni olohun.

Comments

TREADING...

ASIRI ATIBO NINU OGUN AYE (OWU ALANTAKUN)

OWO ALANTAKUN  Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe o nrin lo sugbon hmmmn..... Oku eeyan ni. Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe ije eeyan arare tifi sile sugbon ko mo. Haaaa. O mase oooo........ Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun dina fun eleda re sugbon o nsowipe ori o fomoun shaka lara toun da. Opolopo omo ile iwe ni alantakun aye ti takun di laakaye re. Hmmmmmm Aye toto....... Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun di ariziki re, won wa nfunni owo onje nikan, kosi mo wipe owo igbiyanju lori igbesi aye oun ni won fun oun ki oun bale wa nkan sesi igbesi aye oun. Haaaa owu alantakun, kole di igi kole di irin sugbon tiwon bafi di omo eeyan koleja. Iwo oremi toni anfani lati ma gbomi sare oooo komaba waye lasan, kio si ranti wipe olohun oda e lasan, maduro oooo nitoripe aye gan o duro lasan. Oyeki elomiiran ti ju bayi lo sugbon awu alantakun nko oooo. Owu alantakun ni won figbe elomiiran de ni ko jeki o kuro ni ipo kan bosi ipo gidi sugbon nitoripe o nlosi i...

ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE

ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE, OYA GBO ITUSILE ORO   Mofe so oro nla kan fun awon oni lakaye mosi mo wipe eniti oba farabale yio gbomiye....... 1. Iwo ti o se eyonu awon agbalagba lati kekere titi tio fipe 45 years old laye ti o de sin se lo nitoripe won koti yonu sie na oori ile aye re yanju niyen tabi kin so wipe oori aye wa. 2. Iwo ti o se imule awon agba lati kekere re titi ti o fipe omo 45 years old ti o de sin lo lo nitoripe o si ninu egbe imule won yala ni ita abi ninu gangan oori ile aye wa. 3. Onse ipese awon agba lati kekere re titi tio fidi omo 45 years old lori oro igbesi aye re, igbesi aye re kosi bosi bio se fe oori ile aye wa. 4. Onse ebe awon agba lati kekere re bio Seun bebe Bena lotun se ese si won gba e mu won tun ju e le titi ti o fipe 45 years old o ti ye bebe lati jo joyi na oori ile aye wa. Haaaaaa ma so wipe aseku ni oo rara oo kinse aseku oo, ti bukata re bati biya oti biya nani yen oo, sise ti Otu ntunse bukata re tio ti biya ni ooo, ma j...

ASIRI AYE (GBO ASIRI TOPAMO SI ARA OMO NLE)

IFURA NI OOGUN AGBA... Awon eda kan nbe ninu aye yi tose wipe tia batiri ninu ile kia mase fi ara le fun rara ooo nitoripe bad luck ati opolopo aarun, aisan ninbe lara re, nkan tosi fa po pupo sugbon ejekin so die nibe lati lefi se arawa ni anfaani. OMONLE je eranko kan tose wipe o je CID tabi kia sowipe iranse aburu, olofofo laarin awon alujonu ati eda eniyan, koda iranse awon apakan ninu awon emere ni pelu, bi won se nbe ni Aye nibi beena ni won be lodo awon alujonu na, eleyi lose okunfa fun awon alagbara tiwon da nkan mo ninu awon alujonu ati awa eeyan wipe eranko tobati dawapo iranse lo gbodo maje si arawa, latara bayi iwo omo iyaami loni akiyesi topo ati aifarale fun eranko yi ninu ile re nitoripe iranse buruku niooo. Bio ba njade lo laaro losi ibise tabi ibi nkan rere kan, ti ojure bari OMONLE yi haaaaa olewu fura ooo nitoripe apeere oro nla kan niyen ooo, won fe kio mu rere bo nibiti o nlo nioo. Bio baun bo lati ita tio wa pade OMONLE yi ninu ile gele bio se wole hmmmn n...