Skip to main content

GBOGBO NKAN KONI OOGUN

GBOGBO NKAN KONI OOGUN GBOGBO NKAN SI KONI AJE JOWO KIYESARA.

1.Mase beru lati fe iyawo kio si bimo, bio bati nri owo diedie, ojo ti o ti ni phone ni olohun tin pese credit fun e, maberu, ojo ti eniyan bati ni generator ni olohun yio tima pese owo petrol fun, maberu, ojo ti olohun bati pese motor fun e, ni yio ti ma pese owo petrol fun o nitoripe olohun mowipe arisiki re ti lekun lo se npese oun ti wafi lo fun e, elomiran komo wipe aiti fe iyawo aiti bimo ni koiti jeki oju bayi lo.

2. Jowo tio bati bimo si ita gba omo re wole pada si odo re kio ma fi won ba owo tio baun ri toju re ki arisiki re lema lekun.

3. Gbiyanju lati ma toju alejo daada ki arisiki re lema lekun, mase ni ahun.

4. Gbiyanju kio ma bo enu awon alaini, osese koje wipe ona atila re niyen oo.

5. Olohun yio ma dari jie ti oba ba iyawo re tio ba irawo re mu ninu je wasi fe se afeku owo fun igba die ayafi tio bamu inure dun pada, sugbon tio ba pa iyawo re toba irawo re mu lekun ti omi yo loju re osese ki anu olohun ma bere sini kuro lodo re die die. Jowo ke obinrin nitoripe olohun féran won. Mio so wipe ki o ma bawi o sugbon jeko daju wipe oun ti o bawi le lori fun anfani eyin mejeji ni, kinse lori wipe otini omo obinrin imi, tabi nkan radarada imi.

6. Jowo mase ma ta tete nitori wipe eran awon aje ni eniti o baun ta tete.

7. Abosi, iro pipa, eke, ete buruku, igbonara lori ore ti olohun se fun omo lakeji re, Egan, abuku lati mafi kan eyan, ati beebelo sora nbe ooooo, irinse buruku ni oooo lati le jeki awon aje wo odore.

8. Gbiyanju kio ma gba awe Botie je emeji lose, awe aije aimu nbe, awe aisoro si enikeni lai jade kuro ninu ile, awe aisunmo obinrin fun aimoye ojo tio bamu fun emire.

9. Sora lati ma ju oko fun nkan elemi bi ewure, aguntan, adie, ati beebeloo.

10. Ninu oogun sise sora lati majo nkan ooye pupo nigba gbogbo koribe ba ojumu to emi ni emi nje lodo olohun.
Alukinba........

Comments

TREADING...

ASIRI ATIBO NINU OGUN AYE (OWU ALANTAKUN)

OWO ALANTAKUN  Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe o nrin lo sugbon hmmmn..... Oku eeyan ni. Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe ije eeyan arare tifi sile sugbon ko mo. Haaaa. O mase oooo........ Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun dina fun eleda re sugbon o nsowipe ori o fomoun shaka lara toun da. Opolopo omo ile iwe ni alantakun aye ti takun di laakaye re. Hmmmmmm Aye toto....... Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun di ariziki re, won wa nfunni owo onje nikan, kosi mo wipe owo igbiyanju lori igbesi aye oun ni won fun oun ki oun bale wa nkan sesi igbesi aye oun. Haaaa owu alantakun, kole di igi kole di irin sugbon tiwon bafi di omo eeyan koleja. Iwo oremi toni anfani lati ma gbomi sare oooo komaba waye lasan, kio si ranti wipe olohun oda e lasan, maduro oooo nitoripe aye gan o duro lasan. Oyeki elomiiran ti ju bayi lo sugbon awu alantakun nko oooo. Owu alantakun ni won figbe elomiiran de ni ko jeki o kuro ni ipo kan bosi ipo gidi sugbon nitoripe o nlosi i...

ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE

ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE, OYA GBO ITUSILE ORO   Mofe so oro nla kan fun awon oni lakaye mosi mo wipe eniti oba farabale yio gbomiye....... 1. Iwo ti o se eyonu awon agbalagba lati kekere titi tio fipe 45 years old laye ti o de sin se lo nitoripe won koti yonu sie na oori ile aye re yanju niyen tabi kin so wipe oori aye wa. 2. Iwo ti o se imule awon agba lati kekere re titi ti o fipe omo 45 years old ti o de sin lo lo nitoripe o si ninu egbe imule won yala ni ita abi ninu gangan oori ile aye wa. 3. Onse ipese awon agba lati kekere re titi tio fidi omo 45 years old lori oro igbesi aye re, igbesi aye re kosi bosi bio se fe oori ile aye wa. 4. Onse ebe awon agba lati kekere re bio Seun bebe Bena lotun se ese si won gba e mu won tun ju e le titi ti o fipe 45 years old o ti ye bebe lati jo joyi na oori ile aye wa. Haaaaaa ma so wipe aseku ni oo rara oo kinse aseku oo, ti bukata re bati biya oti biya nani yen oo, sise ti Otu ntunse bukata re tio ti biya ni ooo, ma j...

ASIRI AYE (GBO ASIRI TOPAMO SI ARA OMO NLE)

IFURA NI OOGUN AGBA... Awon eda kan nbe ninu aye yi tose wipe tia batiri ninu ile kia mase fi ara le fun rara ooo nitoripe bad luck ati opolopo aarun, aisan ninbe lara re, nkan tosi fa po pupo sugbon ejekin so die nibe lati lefi se arawa ni anfaani. OMONLE je eranko kan tose wipe o je CID tabi kia sowipe iranse aburu, olofofo laarin awon alujonu ati eda eniyan, koda iranse awon apakan ninu awon emere ni pelu, bi won se nbe ni Aye nibi beena ni won be lodo awon alujonu na, eleyi lose okunfa fun awon alagbara tiwon da nkan mo ninu awon alujonu ati awa eeyan wipe eranko tobati dawapo iranse lo gbodo maje si arawa, latara bayi iwo omo iyaami loni akiyesi topo ati aifarale fun eranko yi ninu ile re nitoripe iranse buruku niooo. Bio ba njade lo laaro losi ibise tabi ibi nkan rere kan, ti ojure bari OMONLE yi haaaaa olewu fura ooo nitoripe apeere oro nla kan niyen ooo, won fe kio mu rere bo nibiti o nlo nioo. Bio baun bo lati ita tio wa pade OMONLE yi ninu ile gele bio se wole hmmmn n...