OLA TINBE FUN OMO ADAMO
Haaaaaaaaaa Ola tinbe fun omo bani Adamo ao mo, ao sife mo, ati gbeju si egbekan, oun la Seun rare la Seun taraka, omo Adamo toun lo alujonu bi won se lagbara to, omo Adamo toun lo raohaniya bi won se lagbara to, omo Adamo ti olohun oba mi fi malaika tiwa peki won ma sowa, omo Adamo ti olohun so ninu awon iwe re wipe oun fiwa se arole oun lori ile, haaaaaaaaaa, omo Adamo tose wipe kosi
ibiti ao le wo yatosi inu orun osini oun tose sababie, omo Adamo tose wipe nitori tiwa ni olohun oba mi se ba esu wi wipe kio kuro lodo toun ti esu na simo wipe nitori omo Adamo lose lemi danu, lofi wa so wipe emi na asima si awon eniyan toun ponle yi lona ti won ni firi alujonu wo, omo Adamo tose wipe bi won ba wonu igbo loba eranko buruku pelu ebun ti olohun funwa awon eranko buruku yi o mo wipe nkan wole to awon omo Adamo toun mu ekun wale
looye Haaaaa Omo Adamo ni sango omi Adamo ni ogun,
omo Adamo ni oya, omo Adamo ni wonnnnn koto di wipe won wole lo, omo Adamo ni anobi sulaimonn lai si omo Adamo hmmmmn mo gbe pamo nitoripe mo ripe imo fe gun mi so oro nla kan, omo Adamo ti olohun sofun wipe epemi nigbakugba ati ni ibikibi lori apata ni lori iyepe ni lori omi ni
lori igi ni lori odan ni ninu akeremodo ni abi ninu ibudo
epemi maaje yin nitoripe mo sun moyin ju isan orun yin lo,
omo Adamo, omo Adamo omo Adamo, omo Adamo tose
wipe ibiti abadoju ija ko Haaaaa olohun oba mi gan fun
rarare yio mo wipe awon eru mi nbinu lowo, omo Adamo
tose wipe kosi bi won se femo oun tiwon pe ni aje laisi omo
Adamo bio badabi iro ibo loti gbo aje abi iroyin aje laise
enu omo Adamo, omo Adamo jowo gbiyanju kio lo mo arare
daaaada kio to dawo le oun kohun, olohun oba mi so wipe
ekoko momi kie to sinmi ti o ba momi bawo lose fe sinmi,
owe loun pa wipe iwo gan funrarare gbiyanju ki o mo arare
ki o mo Ola tinbe fun oo kio to ma pariwo aje aje aje haaaa
afi bi igba tose wipe kosi nkan kan mo ayafi awon aje
nikan, iwo omo bani Adamo ja arare ooo, elomiran ti e tuwa
wa ojuture re ti yio walo se epe abi Olugbohun si ile yio
tuwa mase ebe tabi iyonu tabi imule lolzzzzzz oda gegebi
eniti oun pe yan wa jeun ti Otu wa ndi lowo mu ni oooo, ti o
si mo wipe awon aje ama safun epe tabi Olugbohun se iwo
komo wipe Ase ni olori gbogbo agbara laye ni, eniti obami
oke bafun lase oun lo le kogo aye jaoo, oun nani eniti
gbogbo aye yio mape ni eyan, nitoripe olohun oba fun rarare
gangan lase ooo, lofi si ninu alukurani wipe inamo amuru
isa arada shei an anyekula lahu kunfayakun. ﺇﻧﻤﺎ ﺍﻣﺮﻩ ﺍﺫﺍ ﺍﺭﺍﺩ
ﺷﻲﺀ ﺃﻥ ﻳﻜﻮﻝ ﻟﻪ ﻛﻦ ﻓﻴﻜﻮﻥ Masi mi gbo awon apa kan nbe
ninu omo eda eyan tose wipe Ola tinbe fun e oju oun ti oun
rope oun ni isoro re, haaaa iwo omo iyami don't downgrade
yourself, maja arare wale mo, oke loun niwaju olohun ti oun
je arole fun lori ile ni Ipo re wa oooo, jowo lo wadi arare
daada pelu adura ati awe gbogbo nkan koni ogun ooo, omo
Adamo imi nbe tose wipe oju malaika lo sugbon ko mo
sugbon ma gbagbe wipe nigbati olohun da Adamo tan o
sofun awon malaika wipe ki won fi ori bale nio hmmmn,
awon malaika ti asinwo yi won sunmo olohun daaada oo,
sugbon sibesibe won fi oribale fun awa arole olohun lori ile,
omo Adamo omo Adamo omo Adamo!!! Otan lenu oku ni ikun.
Alukinba aso AGBARA.......

Comments
Post a Comment