Skip to main content

THE CODE (ASIRI ILE AYE)


CODE ( ASIRI TO PAMO) 

Asiri nipa ile aye ni atenu Alukinba Aso Agbara....

Iwo eyan mi nje omo wipe code ni olohun fide ile aye patapata bi ojo koba ro si ile, ile kole mu irugbin gidi jade, nje omo wipe sanmo kan loje fun iyawo re bi o ba ro ojo kan tinbe ni arare (sperm) ko possible ki iyawo re bimo. Se ori wipe bi sanmo se nfun ile ni omi ti ofi nmu irugbin jade beena nani iwo na si iyawo re... hmmmmm.   

Code ni olohun fide ile aye beena ni igbesi aye tie na.
Bi aye yi sewa yi Oni passwords bee sini o ni wrong pin.

Gegebi apeere, woye si remote ati television tinbe ninu ile re wa ri wipe code ni oyinbo fide.
Woye si ATM Machine pelu ATM Card pelu pin re, wari wipe code ni afin se ile aye wa. Bio bati te wrong pin lori awon nkan timo so yi ko possible kio ri owo gba lenu ATM tabi kio gbe television si channel tio fe wo ni kiakia. Ati beebelo woye si dada, opo lobe dada.

Nipa igbesi aye re haaaaaaa code nio, osese kio je wipe aiti mo code re lo nje ki o ma damu ninu aye oooo, osese kio je wipe wrong pin ni onte lati ojoyi ti omo.

1. Elomiran nbe tosewipe ninu ki irun maakun mo lori ni wrong pin re sugbon yio tuma da irun si nani, osese kio je wipe ojoti oba bere sini ge irun re lole ni aye re tofe bere sini ni ojutu dada ooo.
2. Elomiran nbe osese koje wipe aso dudu koba eleda re mu rara rara, yio de mawo, oun ni koje ki igbesi aye re lo bose fe oo.
3. Elomiran nbe irawo re kofe kio ma binu, ti oba ti binu bayi ni awon oore ma sa si eyin fun.
4. Elomiran nbe ninu wrong pin re niki oma mu oti tabi nkan ti yio gbe spirit re kuro nibi ti owa losi ipo miran.
5. Ninu wrong pin elomiran oun niki oma wo aso pupa boti le hun kio kere to lara re, eleda re lema nife si.
6. Wrong pin elomiran oun ni nkan ti onje si enu arare, kiye sara ooo.
7. Elomiran feran kio ma wo abe obinrin tabi abe okunrin ti ibalopo bafe waye, sora osese ki eleda re ko.
8. Ninu wrong pin elomiran oun niki oma bu ebu, koma so oro eyan leyin, ati awon nkan Oni nkan tinbe nile lowo re tabi ti oti na Gegebi owo. Osese koja wipe oun ni onje koma ri owo onje lasan lasan tode je wipe oti koja be.
9. Ninu wrong pin laye yi oun niki elomiran maaje gbese, kiiyesara ki igbesi ayere le da ni kiakia kio yeri ifa seyin mo.
10. Ninu wrong pin elomiran oun niki oma pe kio to sun ni ale. Koda tun ma sun inu okuku haaaaaaa nkan buruku nio. Ati beebeloo.  KIYESARA OOOOO.
Gbiyanju kio ma se adura, saara ati ogun dada. Elomiran yio ma so wipe ogun Koda tabi oun o ni igbinyanju ogun sise, osese ki o ma fi igbesi ayere sere kio ma mo, Haaaaa aye le oo, fura oo. Inu agbole kan kan ti onikaluku ti jade wa loni alagbara aburu sugbon won fi ara pamo fun e nioo. Toba je wipe ki Islam tode tabi ki Christianity tode oogun ni won maun se ninu ile yin ti iwo komo nko? Ni igbinyanju ogun kio si maase adura daada. Mase se aburu si enikeji. Nitoripe ogun loni ojo iponju adura loni ojo gbogbo.
Gbiyanju kio ma kiye si awo. Ala ti o baun la kio si to awon alfa ti won mo Itunmo Ala lo. Won ti so oun ti yio jeki igbesi aye elomiran da fun loju Ala sugbon nitori komo Itunmo re. Won ti so wrong pin elomiran fun loju Ala sugbon komo Itunmo re, won ti so password elomiran fun sugbon komo Itunmo re.

Maro pe nitori oti nri onje je bukata re tibiya, magbagbe wipe onje ko lowa je laye ooo. Awon egbe re nkole, awon egbere nra motor, won ran omo losi ile iwe gidi. Ronu jinle iwo oremi, .. olohun so ninu ALUKURANI WIPE OUN KOFE INIRA FUNYIN IDERA NI OUN FE FUN YIN. Iwo eyan ti ori inira iwo ni onfa opolopo re fun arare ooooo.

Bio bafe iyawo tabi tio bani oko, nje omo wipe olohun yio feran enikan ju enikan lo ninu eyin mejeji? Ti oba je wipe okore ntoju re daada, olohun yio feran okore nitoripe o ntele ase Olohun lara re ojo ti oba tinba ninu je Haaaaa inu ewu nla lowa oo okomo nio Koda igbesi aye awon omo re gan nbe ninu ewu gidi. Beena ni oko na si iyawo re. Kiiyesara ooo.

Elomiran irawo iyare ni onsise fun, ojoti oba ti ko eyin si iyare ni igbesi ayere bere sini daru, beena ni baba re na. KIYESARA OOOO.
Bi ayere koba da boya lole ri ise olore se laye oo. Oni owo.

Comments

Post a Comment

TREADING...

ASIRI ATIBO NINU OGUN AYE (OWU ALANTAKUN)

OWO ALANTAKUN  Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe o nrin lo sugbon hmmmn..... Oku eeyan ni. Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe ije eeyan arare tifi sile sugbon ko mo. Haaaa. O mase oooo........ Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun dina fun eleda re sugbon o nsowipe ori o fomoun shaka lara toun da. Opolopo omo ile iwe ni alantakun aye ti takun di laakaye re. Hmmmmmm Aye toto....... Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun di ariziki re, won wa nfunni owo onje nikan, kosi mo wipe owo igbiyanju lori igbesi aye oun ni won fun oun ki oun bale wa nkan sesi igbesi aye oun. Haaaa owu alantakun, kole di igi kole di irin sugbon tiwon bafi di omo eeyan koleja. Iwo oremi toni anfani lati ma gbomi sare oooo komaba waye lasan, kio si ranti wipe olohun oda e lasan, maduro oooo nitoripe aye gan o duro lasan. Oyeki elomiiran ti ju bayi lo sugbon awu alantakun nko oooo. Owu alantakun ni won figbe elomiiran de ni ko jeki o kuro ni ipo kan bosi ipo gidi sugbon nitoripe o nlosi i...

ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE

ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE, OYA GBO ITUSILE ORO   Mofe so oro nla kan fun awon oni lakaye mosi mo wipe eniti oba farabale yio gbomiye....... 1. Iwo ti o se eyonu awon agbalagba lati kekere titi tio fipe 45 years old laye ti o de sin se lo nitoripe won koti yonu sie na oori ile aye re yanju niyen tabi kin so wipe oori aye wa. 2. Iwo ti o se imule awon agba lati kekere re titi ti o fipe omo 45 years old ti o de sin lo lo nitoripe o si ninu egbe imule won yala ni ita abi ninu gangan oori ile aye wa. 3. Onse ipese awon agba lati kekere re titi tio fidi omo 45 years old lori oro igbesi aye re, igbesi aye re kosi bosi bio se fe oori ile aye wa. 4. Onse ebe awon agba lati kekere re bio Seun bebe Bena lotun se ese si won gba e mu won tun ju e le titi ti o fipe 45 years old o ti ye bebe lati jo joyi na oori ile aye wa. Haaaaaa ma so wipe aseku ni oo rara oo kinse aseku oo, ti bukata re bati biya oti biya nani yen oo, sise ti Otu ntunse bukata re tio ti biya ni ooo, ma j...

ASIRI AYE (GBO ASIRI TOPAMO SI ARA OMO NLE)

IFURA NI OOGUN AGBA... Awon eda kan nbe ninu aye yi tose wipe tia batiri ninu ile kia mase fi ara le fun rara ooo nitoripe bad luck ati opolopo aarun, aisan ninbe lara re, nkan tosi fa po pupo sugbon ejekin so die nibe lati lefi se arawa ni anfaani. OMONLE je eranko kan tose wipe o je CID tabi kia sowipe iranse aburu, olofofo laarin awon alujonu ati eda eniyan, koda iranse awon apakan ninu awon emere ni pelu, bi won se nbe ni Aye nibi beena ni won be lodo awon alujonu na, eleyi lose okunfa fun awon alagbara tiwon da nkan mo ninu awon alujonu ati awa eeyan wipe eranko tobati dawapo iranse lo gbodo maje si arawa, latara bayi iwo omo iyaami loni akiyesi topo ati aifarale fun eranko yi ninu ile re nitoripe iranse buruku niooo. Bio ba njade lo laaro losi ibise tabi ibi nkan rere kan, ti ojure bari OMONLE yi haaaaa olewu fura ooo nitoripe apeere oro nla kan niyen ooo, won fe kio mu rere bo nibiti o nlo nioo. Bio baun bo lati ita tio wa pade OMONLE yi ninu ile gele bio se wole hmmmn n...