ELEYI NI TURARI AGBARA NLA TI AFINLE EMI AIRI BUBURU JADE NINU ILE.
ELEYI NI TURARI AGBARA NLA TI AFINLE EMI AIRI BUBURU JADE NINU ILE.
AKO ALANGBA TI ORIRE PON DAADA MERINDINLOGUN, ABO ALANGBA MERINDINLOGUN, OPOLOPO EESO WERENJEJE TOPO, IKODE MERINDINLOGUN, EWE AJEOFOLE EGBERUN KAN OLENI IGBA 1,200, EEPO OBO, EPO IGINLA, OPOLOPO EWE OMISINMISIN GOGORO, TURARU ALIMISIKI GBEREFU, TURARI TUFAU L JINNU, IKUN OJIA, TURARI LUBAN SAKARA, AO GUN GBOGBO RE PAPO, AO KO SINU ASO ASUNWON EYITI AFI ASO FUNFUN ATI DUDU RAN, AO MAFIN NI DEEDE AGOGO MEJILA ALE, (12 P.M).
EEWO NI TURARI YI FUN EYIKEYI NINU AWON EMI OKUNKUN LATI FI OJU RI EEFIN TURARI YI TABI LATI GBO OORUN TURARI NA, ODI DANDAN KI IRU EMI BE FI AYE SILE NI TIPA TIPA BI BEEKO YIO PADANU AGBARA RE YIO SI DI OKAN YEPERE LAARIN AWON EMI AIRI BUBURU EGBE RE, WON YIO SILE KURO LAARIN AWON EMI BUBURU EGBERE, NITORI WIPE ATI GBA ASE ATI OHUN IMUSE AGBARA KURO NI OWORE.
I need this turari sir
ReplyDeletePlease, let me have your phone number, this is my WhatsApp number 08133926480
ReplyDeleteWhat's your number
ReplyDelete