Bi o ba la Ala wipe eyin re yo tabi o kan. Opolopo eniyan ni o ma n la ala wipe eyin toun yo tabi eyin toun kan hmmmn Ala yi ni agbara pupo sugbon opolopo wa ni ao ka Ala yi si nkankan haaaa ayafi kio sora Olohun oba feran re lose ntu asiri fun e. Bio ba la ala wipe eyin re yo, Ala yi ntunmo si wipe kio sora pupo pupo pelu imafi enure se epe nitoripe eyin re loju ala ntunmo si Ase (Command), won so fun e wipe kio sora lati binu so oro odi nigba kugba boya ti ibinu bade, awon yoruba sowipe epe ti olu ife koko ra lojosi akobi omo lofi pa hmmnnn, sora lati so oro odi sinu igbesi aye awon omo re, okore, tabi alasunmo bi oloore re ki iwona maba padanu nkan meji tinse Ase enu re ati nkan pataki kan ninu igbesi aye re. Kiloma nfa iru ala bayi? Oun nani wipe Olohun oba fe jeki oso arare pelu opolopo Adura ijanu ati saara iso enu, ni awon yoruba fi sowipe ki eeyan lo bo enu re tinse oluboborotiribo awo enu. Eyin ase ati eyin onkan wa koni fiwale si aye lo ooo.
OWO ALANTAKUN Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe o nrin lo sugbon hmmmn..... Oku eeyan ni. Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe ije eeyan arare tifi sile sugbon ko mo. Haaaa. O mase oooo........ Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun dina fun eleda re sugbon o nsowipe ori o fomoun shaka lara toun da. Opolopo omo ile iwe ni alantakun aye ti takun di laakaye re. Hmmmmmm Aye toto....... Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun di ariziki re, won wa nfunni owo onje nikan, kosi mo wipe owo igbiyanju lori igbesi aye oun ni won fun oun ki oun bale wa nkan sesi igbesi aye oun. Haaaa owu alantakun, kole di igi kole di irin sugbon tiwon bafi di omo eeyan koleja. Iwo oremi toni anfani lati ma gbomi sare oooo komaba waye lasan, kio si ranti wipe olohun oda e lasan, maduro oooo nitoripe aye gan o duro lasan. Oyeki elomiiran ti ju bayi lo sugbon awu alantakun nko oooo. Owu alantakun ni won figbe elomiiran de ni ko jeki o kuro ni ipo kan bosi ipo gidi sugbon nitoripe o nlosi i...