Skip to main content

Posts

Showing posts from March, 2018

ASIRI ATIBO NINU OGUN AYE (OWU ALANTAKUN)

OWO ALANTAKUN  Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe o nrin lo sugbon hmmmn..... Oku eeyan ni. Opolopo eeyan lonbe laye tose wipe ije eeyan arare tifi sile sugbon ko mo. Haaaa. O mase oooo........ Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun dina fun eleda re sugbon o nsowipe ori o fomoun shaka lara toun da. Opolopo omo ile iwe ni alantakun aye ti takun di laakaye re. Hmmmmmm Aye toto....... Opolopo eeyan ni alantakun aye ti takun di ariziki re, won wa nfunni owo onje nikan, kosi mo wipe owo igbiyanju lori igbesi aye oun ni won fun oun ki oun bale wa nkan sesi igbesi aye oun. Haaaa owu alantakun, kole di igi kole di irin sugbon tiwon bafi di omo eeyan koleja. Iwo oremi toni anfani lati ma gbomi sare oooo komaba waye lasan, kio si ranti wipe olohun oda e lasan, maduro oooo nitoripe aye gan o duro lasan. Oyeki elomiiran ti ju bayi lo sugbon awu alantakun nko oooo. Owu alantakun ni won figbe elomiiran de ni ko jeki o kuro ni ipo kan bosi ipo gidi sugbon nitoripe o nlosi i...

ASIRI AYE (GBO ASIRI TOPAMO SI ARA OMO NLE)

IFURA NI OOGUN AGBA... Awon eda kan nbe ninu aye yi tose wipe tia batiri ninu ile kia mase fi ara le fun rara ooo nitoripe bad luck ati opolopo aarun, aisan ninbe lara re, nkan tosi fa po pupo sugbon ejekin so die nibe lati lefi se arawa ni anfaani. OMONLE je eranko kan tose wipe o je CID tabi kia sowipe iranse aburu, olofofo laarin awon alujonu ati eda eniyan, koda iranse awon apakan ninu awon emere ni pelu, bi won se nbe ni Aye nibi beena ni won be lodo awon alujonu na, eleyi lose okunfa fun awon alagbara tiwon da nkan mo ninu awon alujonu ati awa eeyan wipe eranko tobati dawapo iranse lo gbodo maje si arawa, latara bayi iwo omo iyaami loni akiyesi topo ati aifarale fun eranko yi ninu ile re nitoripe iranse buruku niooo. Bio ba njade lo laaro losi ibise tabi ibi nkan rere kan, ti ojure bari OMONLE yi haaaaa olewu fura ooo nitoripe apeere oro nla kan niyen ooo, won fe kio mu rere bo nibiti o nlo nioo. Bio baun bo lati ita tio wa pade OMONLE yi ninu ile gele bio se wole hmmmn n...

TURARI AGBARA TI AFIN LE EMI BUBURU JADE..

ELEYI NI TURARI AGBARA NLA TI AFINLE EMI AIRI BUBURU JADE NINU ILE.   ELEYI NI TURARI AGBARA NLA TI AFINLE EMI AIRI BUBURU JADE NINU ILE. ENIKENI YIO WU TI AWIN EMI BUBURU (EVIL SPIRIT) BA NDA LAAMU NINU ILE TIWON KOSI JEKI AWON IYAWO ATI OMO NI ISINMI, TIWO DERU BAWON NINU ILE NA NIPA YIYO SIWON LOJU ALA ABI LOJU AYE GANGAN, PAAPA NIGBATI OKUNKUN BANBE TABI KI AWON ARAALE MAAGBO ORISIRISI OHUN, TABI IPA ESE TIWON KOSI RI AWON TINRIN LO.  AKO ALANGBA TI ORIRE PON DAADA MERINDINLOGUN, ABO ALANGBA MERINDINLOGUN, OPOLOPO EESO WERENJEJE TOPO, IKODE MERINDINLOGUN, EWE AJEOFOLE EGBERUN KAN OLENI IGBA 1,200, EEPO OBO, EPO IGINLA, OPOLOPO EWE OMISINMISIN GOGORO, TURARU ALIMISIKI GBEREFU, TURARI TUFAU L JINNU, IKUN OJIA, TURARI LUBAN SAKARA, AO GUN GBOGBO RE PAPO, AO KO SINU ASO ASUNWON EYITI AFI ASO FUNFUN ATI DUDU RAN,  AO MAFIN NI DEEDE AGOGO MEJILA ALE, (12 P.M).  EEWO NI TURARI YI FUN EYIKEYI NINU AWON EMI OKUNKUN LATI FI OJU RI EEFIN TURARI YI TABI LATI...

ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE

ASIRI ALUYO ATI ASEYORI NINU AYE, OYA GBO ITUSILE ORO   Mofe so oro nla kan fun awon oni lakaye mosi mo wipe eniti oba farabale yio gbomiye....... 1. Iwo ti o se eyonu awon agbalagba lati kekere titi tio fipe 45 years old laye ti o de sin se lo nitoripe won koti yonu sie na oori ile aye re yanju niyen tabi kin so wipe oori aye wa. 2. Iwo ti o se imule awon agba lati kekere re titi ti o fipe omo 45 years old ti o de sin lo lo nitoripe o si ninu egbe imule won yala ni ita abi ninu gangan oori ile aye wa. 3. Onse ipese awon agba lati kekere re titi tio fidi omo 45 years old lori oro igbesi aye re, igbesi aye re kosi bosi bio se fe oori ile aye wa. 4. Onse ebe awon agba lati kekere re bio Seun bebe Bena lotun se ese si won gba e mu won tun ju e le titi ti o fipe 45 years old o ti ye bebe lati jo joyi na oori ile aye wa. Haaaaaa ma so wipe aseku ni oo rara oo kinse aseku oo, ti bukata re bati biya oti biya nani yen oo, sise ti Otu ntunse bukata re tio ti biya ni ooo, ma j...

ASIRI BIBO LOWO EMI OKUNKUN

  IWULO KURISIYU  Iwo oremi kurisiyu di owo re bio bafe sun ni ale, maro wipe iwo nikan ni o ngbe inu ile ooo awon kan nbe ti won ti siwaju re de ibe tipetipe kio to ko ile sibe. Aye ni gbangba beena lotu ni odi keji pelepele di owo re gbiyanju kio maka kurisiyu daada kio lefi emire le Olohun lowo. Gbiyanju kio sofun awon Alfa wipe ki won ba e han kurisiyu yi papo mo suratu yaasin pelu awon ayat Iso ninu Al Quran kio mafi won inu ile re osese koje wipe eleyi lo nfa sababi idiwo ati idena koda alakala ati beebelo. Aye pe igba ooo.  Adura ati isunmo awon eni olohun di owore. Iwo oremi kurisiyu di owo re bio bafe sun ni ale, maro wipe iwo nikan ni o ngbe inu ile ooo awon kan nbe ti won ti siwaju re de ibe tipetipe kio to ko ile sibe. Aye ni gbangba beena lotu ni odi keji pelepele di owo re gbiyanju kio maka kurisiyu daada kio lefi emire le Olohun lowo. Gbiyanju kio sofun awon Alfa wipe ki won ba e han kurisiyu yi papo mo suratu yaasin pelu awon ayat Iso ninu Al Q...

AMORAN LORI BUSINESS (OWO SISE)

OJA TITA Oro re nipa oja tita fun iwo onisowo oja tabi ise owo (handwork) lokunrin ati lobinrin. Kilo ma nfa gan ki eeyan mase ta tabi ki eeyan mase mata Ata jere tabi ki a mari owo re koduro lowo lati fi se nkan ire hmmmn gbiyanju kio lo se akiyesi awon nkan won yi nitori ife ti emi Alukinba nisi gbogbo aye latara Olohun oba. 1. Osese kio je elegbe, ki awon egbere si maferan oja ti o nta, for example ije elegbe re romo ibi omi ti o ba nta awon iran eja kan yio ma bie leere Lori aje re. Elekeji nbe niwipe kio lomo saara toye fun awon egbere, lo gbiyanju lori eniti awon agbalagba npeni oko orun tabi oko oru eyi tose wipe yio wama ba e Sun loju ala, bi nkan yi ba nsele ariziki re yio ma se segesege. Ati beebelo. 2. Gbiyanju kio lomo iru ojo toba irawo re mu, boya irawo iyepe ni iwo nlo ni Abi irawo omi, ategun Abi ina. Eleyi ni yio so iru ise tio le se jere fun o. Eleyi ni yio jeki omo nkan eewo tiko yeki o maje si enure tabi kio mase, gbogbo awon nkan wonyi loni se pelu ariz...

THE CODE (ASIRI ILE AYE)

CODE ( ASIRI TO PAMO)  Asiri nipa ile aye ni atenu Alukinba Aso Agbara.... Iwo eyan mi nje omo wipe code ni olohu n fide ile aye patapata bi ojo koba ro si ile, ile kole mu irugbin gidi jade, nje omo wipe sanmo kan loje fun iyawo re bi o ba ro ojo kan tinbe ni arare (sperm) ko possible ki iyawo re bimo. Se ori wipe bi sanmo se nfun ile ni omi ti ofi nmu irugbin jade beena nani iwo na si iyawo re... hmmmmm.    Code ni olohun fide ile aye beena ni igbesi aye tie na. Bi aye yi sewa yi Oni passwords bee sini o ni wrong pin. Gegebi apeere, woye si remote ati television tinbe ninu ile re wa ri wipe code ni oyinbo fide. Woye si ATM Machine pelu ATM Card pelu pin re, wari wipe code ni afin se ile aye wa. Bio bati te wrong pin lori awon nkan timo so yi ko possible kio ri owo gba lenu ATM tabi kio gbe television si channel tio fe wo ni kiakia. Ati beebelo woye si dada, opo lobe dada. Nipa igbesi aye re haaaaaaa code nio, osese kio je wipe aiti mo code re lo nje ki o ma...

INFORMATION ABOUT JINN

Information about jins Allah says (and He created the jinn and mankind only to worship) The jins see us but we do not see them because Allah has made a membrane in the eyes of  man so that we do not see them because if we see them we might die of fear or become blind because of the shock. Their sight is really terrifying . They always live around us and there are 3 types of them : ➖Elifrit -this ones have the ability to transfer things from one country to another and they are used by witches and sorcerers ➖Alkhabal- these are the freaks of the jin and they disturb man such as wearing their clothes, eplilepsy and so on ➖Ghilan- They appear in form of man,cat, dog, donkey, or any animal. Generally? All of them are weak and they flee when they hear Surat Yassin, muawadhatein, or surat baqarah. Therefore I advise you dear muslim brother or sister; 1. When you change your clothes say bismillahi Rahmani Raheem, so that they don't see your nakedness. 2. When you sleep, s...

ALAYE LORI ALA LILA

ALA LILA Omo iya mi mofe kio mo wipe Ala lila je ona pataki kan ti Olohun ma ngba ba eda re soro, oore nla nifun e bio bamo tunmo re sugbon aburu ni ooo ti o koba mo itunmo re. Gbogbo botile hun ki enina je nitoripe Aanu Olohun to Kari aye ni ala lila je gbogbo eeyan sini yio ma lala ayafi awon kankan ti wahala ba nbefun emi won tabi eniti iyare ba nse nkan osu lori oyun re ati beebelo. 1.Ti ile bati su mase ma ro Ala fun eeyan nitoripe awon emi orisirisi tin jade nigbana won sile so oro ana di nkan imiran mo eeyan lowo. 2. Mase ma ro Ala fun enikeni toba ti ri, gbiyanju kio ro Ala re fun eniti o mo wipe oda e loju wipe o mo Ala tu daada nitoripe ti eeyan bafe ro Ala fun eeyan malaaika tinbe ni incharge Ala re yio sokale lati fi ase si nkan ti eniyi basi tu fun e nani yio se mo e lara...toba tu Ala daada fun e ni aburu hmmm aburu nani yio fe sele. 3. Gbiyanju kio trust eniti o fe ro Ala re fun wipe kio ba e tu nitoripe hmmmn awon eeyan nbe ti won tiri orire re latara Ala re...

ALAYE LORI AWON ELEIYE (AJE)

ELEYI NI ALAYE NI WONBA BOTI LE DA ARARE MO NI WONBA. .......... Ninu gbogbo nkan laye OYE Se pataki pupo nitori wipe oye gangan lagba nwo, iwona gbiyanju ki o woye si arare latara awon nkankan ninu arare boya latara bayi iwona wa da arare mo, ti eniyan bawo ifa fun e kosi aburu nbe bi eniyan bawo iyepe fun e kosi aburu nbe sugbon lodo temi oo yato si ki eniti oun wo nko fun e lo Iriran tabi onmo Haaa oye ju gbogbo e lo oo nitoripe opolopo oun ti won ba so fun e oye loma fi gbe opolopo ninu e, latara bayi jowo bami woye si awon nkan ti mofe ka kale yi. 1. Ala ti o maun saba nla ni igba gbogbo, jowo se o maun Segun loju alare ni abi o kinsegun? 2. Se ala dada lo maun lani abi abi ala buruku. Bio bawa la ti aburu se o maun Segun? 3. Loju aye gangan se okan re maun bale lori igbesi aye re abi koda e loju? 4. Awon obi re inu ogun wo ni won wa abi se won kosi ninu ogun kankan? 5. Iyawo Melo ni baba re fe ipowo deni iya re wa laarin won. That will be competition among childr...

ONA LATI DARA RE MO

ELEYI NI ALAYE NI WONBA BOTI LE DA ARARE MO NI WONBA ........... Ninu gbogbo nkan laye OYE Se pataki pupo nitori wipe oye gangan lagba nwo, iwona gbiyanju ki o woye si arare latara awon nkankan ninu arare boya latara bayi iwona wa da arare mo, ti eniyan bawo ifa fun e kosi aburu nbe bi eniyan bawo iyepe fun e kosi aburu nbe sugbon lodo temi oo yato si ki eniti oun wo nko fun e lo Iriran tabi onmo Haaa oye ju gbogbo e lo oo nitoripe opolopo oun ti won ba so fun e oye loma fi gbe opolopo ninu e, latara bayi jowo bami woye si awon nkan ti mofe ka kale yi. 1. Ala ti o maun saba nla ni igba gbogbo, jowo se o maun Segun loju alare ni abi o kinsegun? 2. Se ala dada lo maun lani abi abi ala buruku. Bio bawa la ti aburu se o maun Segun? 3. Loju aye gangan se okan re maun bale lori igbesi aye re abi koda e loju? 4. Awon obi re inu ogun wo ni won wa abi se won kosi ninu ogun kankan? 5. Iyawo Melo ni baba re fe ipowo deni iya re wa laarin won. That will be competition among children...

AMORAN LORI OOGUN FUNFUN

OOGUN FUNFUN Gbiyanju kio lomo nipa oogun funfun nitoripe gbogbo eeyan koni oogun dudu ba lara mu. Oogun dudu yio mu owo wafun eeyan sugbon kosi igbati o ni pada broke again nkan sini se pelu ariziki re oun lofa lofi je wipe ko gbodo maje nkan ojojumo, pele pele di owo wa.  Sugbon oogun funfun ki nsebe kosi ni mu owo ojiji wa fun eeyan koda yio tuma lekun imole arare latara eelo ti abafise. Apere eelo oogun funfun re kio bale mo wipe onbe gegebi Olohun base fi imo mo onikaluku wa. Omi okun ati iyepe re. Omi osa ati iyepe re.  Omi inu apata. Omi odo ti o nsan. Omi ojo oferefe.  Omi ara eeso (oloju eeso). Ose funfun balau bi joy Abi lux nigbamiran ose colour orisirisi yatosi black soap. Eja odo bi pakura tabi eja alawo funfun. Awo funfun balau tiko ni abawon.  Aso funfun. Lofinda to ni oorun daada tabi perfume. Awon ewe kan wa nbe mofi Olohun bura funfun niwon awon ewe kan sinbe tiwon je dudu ati awon colour imiran na hmmmn ona imo jin...

GBOGBO NKAN KONI OOGUN

GBOGBO NKAN KONI OOGUN  GBOGBO NKAN SI KONI AJE JOWO KIYESARA . 1.Mase beru lati fe iyawo kio si bimo, bio bati nri owo diedie, ojo ti o ti ni phone ni olohun tin pese credit fun e, maberu, ojo ti eniyan bati ni generator ni olohun yio tima pese owo petrol fun, maberu, ojo ti olohun bati pese motor fun e, ni yio ti ma pese owo petrol fun o nitoripe olohun mowipe arisiki re ti lekun lo se npese oun ti wafi lo fun e, elomiran komo wipe aiti fe iyawo aiti bimo ni koiti jeki oju bayi lo. 2. Jowo tio bati bimo si ita gba omo re wole pada si odo re kio ma fi won ba owo tio baun ri toju re ki arisiki re lema lekun. 3. Gbiyanju lati ma toju alejo daada ki arisiki re lema lekun, mase ni ahun. 4. Gbiyanju kio ma bo enu awon alaini, osese koje wipe ona atila re niyen oo. 5. Olohun yio ma dari jie ti oba ba iyawo re tio ba irawo re mu ninu je wasi fe se afeku owo fun igba die ayafi tio bamu inure dun pada, sugbon tio ba pa iyawo re toba irawo re mu lekun ti omi yo loju r...

AMORAN KORI IGBESI AYE

AMORAN LORI AAJO SISE NINU AYE Mofe so oro nla kan fun awon oni lakaye mosi mo wipe eniti oba farabale yio gbomiye....... 1. Iwo ti o se eyonu awon agbalagba lati kekere titi tio fipe 45 years old laye ti o de sin se lo nitoripe won koti yonu sie na oori ile aye re yanju niyen tabi kin so wipe oori aye wa. 2. Iwo ti o se imule awon agba lati kekere re titi ti o fipe omo 45 years old ti o de sin lo lo nitoripe o si ninu egbe imule won yala ni ita abi ninu gangan oori ile aye wa. 3. Onse ipese awon agba lati kekere re titi tio fidi omo 45 years old lori oro igbesi aye re, igbesi aye re kosi bosi bio se fe oori ile aye wa. 4. Onse ebe awon agba lati kekere re bio Seun bebe Bena lotun se ese si won gba e mu won tun ju e le titi ti o fipe 45 years old o ti ye bebe lati jo joyi na oori ile aye wa. Haaaaaa ma so wipe aseku ni oo rara oo kinse aseku oo, ti bukata re bati biya oti biya nani yen oo, sise ti Otu ntunse bukata re tio ti biya ni ooo, ma jeki ete won mu e mole oo ...

OLA TINBE FUN OMO ADAMO

OLA TINBE FUN OMO ADAMO Haaaaaaaaaa Ola tinbe fun omo bani Adamo ao mo, ao sife mo, ati gbeju si egbekan, oun la Seun rare la Seun taraka, omo Adamo toun lo alujonu bi won se lagbara to, omo Adamo toun lo raohaniya bi won se lagbara to, omo Adamo ti olohun oba mi fi malaika tiwa peki won ma sowa, omo Adamo ti olohun so ninu awon iwe re wipe oun fiwa se arole oun lori ile, haaaaaaaaaa, omo Adamo tose wipe kosi ibiti ao le wo yatosi inu orun osini oun tose sababie, omo Adamo tose wipe nitori tiwa ni olohun oba mi se ba esu wi wipe kio kuro lodo toun ti esu na simo wipe nitori omo Adamo lose lemi danu, lofi wa so wipe emi na asima si awon eniyan toun ponle yi lona ti won ni firi alujonu wo, omo Adamo tose wipe bi won ba wonu igbo loba eranko buruku pelu ebun ti olohun funwa awon eranko buruku yi o mo wipe nkan wole to awon omo Adamo toun mu ekun wale looye Haaaaa Omo Adamo ni sango omi Adamo ni ogun, omo Adamo ni oya, omo Adamo ni wonnnnn koto di wipe won wole lo, omo Adamo ni anobi s...